Search Articles on this Blog

Wednesday, December 7, 2016

From the table of YORSA (Yoruba Language students association) President, Aare Busari Abdulwaheed

From the table of YORSA (Yoruba Language students association) President, Aare Busari Abdulwaheed

Tiwa lasa! Tiwa nisese!
Apapo gbogbo omo egbe akeeko imo ijinle ati ede Yoruba nfi asiko yi pe gbogbo akeeko Yoruba ati awon akeeko ile eko olukoni agba ti ipinle Kwara ti o kale si ilu Ilorin, lati was fi ijoko ye won si nibi ayeye itonisona ati isalaye ohun ti a npe ni coed Ilorin fun awon akeeko titun ti won se wole (orientation for freshers)..wiwa yin ni idunnu ati iwuri tiwa.
IKEDE: Dan Dan ni fun awon akeeko Yoruba pata lati Odun kini si iketa lati wo aso ibile/asa (local attire) wa sibi ayeye naa tori ki aponle le wa fun wa.. Eseun pupo.
Tiwa lasa!!! Tiwa nisese!!!
Rere dodo!!! Rere dodore!!!
Isese a gbe wa o.. Oduduwa o ni fiwa sile..

Ojo: ojo keejo (8), osu kejila (12), egberun odun meji le ni merindinlogun(2016)
Aaye: yara ikekoo ikerin(hall 4)
Akoko: aago mewa (10am)

Ikede yii wa lati odo Aare busari abdulwaheed,olori oko kaafata fun gbogbo akeeko Yoruba..
Olukede: Ogbeni Owodunni Lukmon Olayinka (Lyrical)

Powered by.Campusechoe ©2016
Www.campusechoe.blogspot.com

No comments:

Post a Comment

What do you think about this write up? Please comment